Home Music Yoruba Hymns & Audio Sure Fun Wa Loni Lyrics

Sure Fun Wa Loni Lyrics

1

1. SURE fun wa loni, Baba wa orun
A gboju wa soke si O,
We to sure f’Abraham
baba wa,
Jowo sure fun wa.

Egbe: Alpha ati Omega

A si okan wa paya fun O,
Ma je ka lo Iofo.

2. Metalokan Mimo Alagbara
lfe to jinle julo
Awamaridi Olodumare
Jo f’ire kari wa.

Egbe: Alpha ati Omega…

3. Awa nke pe O loni, Baba wa,
Ma je k’omo Re rahun
Ko sohun ti jamo lehin ekun
Jowo dabobo wa.

Egbe: Alpha ati Omega…

4. Wo lo m’omi lat’inu apata
F’awon enia Re saju
O rojo manna pelu lat’orun
Jowo pese fun wa.

Egbe: Alpha ati Omega
A si okan wa paya fun O,
Ma je ka lo Iofo. Amin


Join our WHATSAPP WHATSAPP CHANNEL or TELEGRAM CHANNEL for instant updates

1 COMMENT

Leave A Reply

Please enter your comment!
Please enter your name here